Bi iṣẹlẹ naa se waye ni ọpọ iwadii ti bẹrẹ lori lati dena aisan yii lawujọ ni orilẹede Naijiria ati ni ilẹ UK.